Home / Art / Àṣà Oòduà / Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun
apc

Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun

Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won fe lo gege bi igbakeji re. Sugbon titi di akoko yii, a ko le ti so boya Faleke faramo aba lati di igbakeji okunrin naa.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti