Home / Art / Àṣà Oòduà / Ounje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)

Ounje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)

……………………………………………………….
Iwe-Iroyin ‪#‎AYEKOOTO_MAGAZINE‬ fun T’osu kerin ti jade sita bayii, ‪#‎Ogorun‬ naira #100 ni beere fun tire lodo ‪#‎VENDOR‬ nibi-kibi
……………………………………………………………
AMOYE TONII : ‪#‎ARABINRIN_FOLASHADE_TEMITOPE‬
…………………………………………………………..
………………………………….
HUN !!!
‪#‎Iya‬ to je omo f’ogun ‪#‎Odun‬ ..
‪#‎Osi‬ to ta omo f’ogbon ‪#‎Osu‬ ..
Bi ko ba pa omo …
A sin leyin re ..
………………..
WOO ORE WA !!!
Bi ‪#‎Oluko‬ laye je
Bi a ba se gbe ibe si
la see k’ogbon-mogbon
………………..
GBOMI DAADAA ORE WA !!!
‪#‎Iriri_aye‬ kan kii ti nii pa
‪#‎Ogbon‬ bayii nii mu koni
‪#‎Idojukoo‬ re oni kii sopin ‪#‎Aye‬
‪#‎Isoro‬ oni kii se titi-lai
……………………………..
DAKUN ORE WA !!!
Maa ranti pe Ohun to le nbo waa dero..
‪#‎Adura‬ pelu ‪#‎Igbiyanju‬ leda fi n bori ogun laye..
…………………………….
A KU OJUMO
A Ku Amojuba ‪#‎Osu_Tuntun‬ (APRIL)
A tun ku Ojo-nla ‪#‎JIMOH‬ tonii
Opo Oloyin ati Alayo bee la o dijo maa se loke Eepe lase ‪#‎EDUMARE‬ ..

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti