* Kin ni nje ELA ? Abi Taani #ELA je gan-an ?
* Nje ESIN ati #ASA Yoruba tako ara won
bi ?
* Bawo ni # Ela_boru , Ela Boye ,
Ela bo sise se je Ede ikini fun awon Babaalawo ?
E yin redio(radio) yin si ikanni #UNIQ_103
.1FM, Ilesa, ni dede agogo mewaa abo
owuro (10:30am) oni; fun akotun eto
#ISESE_OMO_OODUA Rere.