Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo
igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo
itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je
fun gbogbo wa lase Edumare(Ase).
# AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i re,
niwon igba ti obi i re n be laye; eyin ti E ko
ba ni obi laye mo, E maa se saara fun oku
orun. E ranti wipe #Iya ni wura, #Baba ni
dingi. Ayo ni ooo.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

