Home / Art / Àṣà Oòduà / Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo 
boko haram

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo 

NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà tí owó àwon ológun ti bà.
       Oba so fún àwon oníròyìn ní ààfin rè ní Auchi ní àgbáríjo ìjoba ìbílè ìwò oòrùn ní ìjoba ìbílè náà, wípé apàse ilé-ìwé ológun orílè èdè Nàìjíríà NICOHO ní agbègbè Auchi, fi tó o létí nípa mímú àwon afurasí náà. “kí ó tó di wípé o wolé, mo ti ní òrò pèlú apàse “.
 “ó fi oun tí won ń se tó mi tó mi létí àti bíwon se mú okòó lé mérin (24) àwon afurasí yi Boko Haram tí won sisé bí fúlàní darandaran “.ó so béè.
   “Apàse tún fi tó mi létí wípé àwon afurasí yí won máa darí won lo sí Benin “Oba so béè.
Ó gbé oríyìn fún apàse fún ìgbésè takuntakun tí ó gbé  láti bá àwon afurasí náà wo ìjàkadi nínú aginjù
 Ó so wípé “ètò ìdáàbòbò ní láti se àmójútó fínífíní “,
 Otaru sàpéjùwé ètò àwon darandaran lágbègbè won wípé óburú jàè so pé ” A ti be àwon àgbè, papàá jùlo àwon obìnrin láti má lo sí oko ní àkókò yí.
  A fún won ní owó díè láti jé kí won máa se isé tí owó won bá fún ìgbà díè náà. Tí gbogbo rè máa fi yanjú.
   Àwon ìgbìmò ìbílè ń jùmò sisé pò pèlú àwon ológun, àwon olùdáàbòbò ìlú asì ti fi tó àwon olóde létí láti wá ònà àbáyo tó dángájíá sí òrò náà “ó fi kun

English Version
Continue after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti