Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).
Ìyá Ń Dá

Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).

Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ó se múra látòkè délè bí okùnrin, “ó sì ko “a kú ayeye àjòdún baba sí gbogbo àwon ìyá ń dá gbé n’íta”…
Àwòrán míràn léyìn ìjáde

 

Continue after the page break for the English version.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti