Home / Art / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan tí won lé kúrò ní ilù òyìnbó wá sí orílé èdè Nàìjíríà nígbà tí omo rè obìnrin wà ní odún méjo (8) ti fi ara hàn nígbà tí omo rè kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè U.S.

Arákùnrin kan tí won lé kúrò ní ilù òyìnbó wá sí orílé èdè Nàìjíríà nígbà tí omo rè obìnrin wà ní odún méjo (8) ti fi ara hàn nígbà tí omo rè kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè U.S.

    Yàtò sí wípé ó n kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti a mò sí ‘Morgan state university’, ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mò sí Esther Ayomide tún ní èbún pàtàkì tí ó n dúró dèé ní ojó èye rè.

Gégé bí ó se so, bàbá rè tí won lé kúrò ní ìlú Òyìnbó nígbà tí ó wà ní omo odún méjo fi ara hàn bí ojó èye rè, sùgbón omobìnrin yí kò bìkítà ó sún ekún gan ni.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...