Home / Art / Àṣà Oòduà / Arewà tí ó se ìgbéyàwó láì kun nkankan sí ojú ní ojó èye rè .

Arewà tí ó se ìgbéyàwó láì kun nkankan sí ojú ní ojó èye rè .

 

Èyin òdóbìnrin ; njé èyin le múra báyìí ní ijó ìgbéyàwó yín bí? Gbogbo obìnrin ni ó máa n gbèrò láti dàbí egbin ní ojó ìgbéyàwó won , gbogbo ònà ni won yóò sì wá láti jékí èróngbà won di síse .
Sùgbón ìyàwó yí ní tirè gbèrò láti kun nkankan ní ojó èye rè .

Èyin obìnrin n’íta njé èyin le se èyí bí….

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

yemoja 2026

Yoruba Yemoja float with 10,000 Litres of water by Mocidade Alegre Won the São Paulo Carnival 2026 in Brazil!

This majestic allegorical float, a viral sensation during the parade, featured Yemoja (Iemanjá) Yemoja was powerfully incorporated because the enredo “Malunga Léa – Rapsódia de uma Deusa Negra” was a heartfelt tribute to the late legendary Brazilian actress Léa Garcia (1930–2023). A pioneering African icon in theater, film, and TV (famous for roles like in Escrava Isaura and her work with Teatro Experimental do Negro). The theme celebrated her as a “deusa negra” (“Black” Goddess): her resilience, ancestral strength, female ...