Home / Art / Àṣà Oòduà / Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko.
Bákan náà, won tún sí ojú olú polówó ojà won tí a mò sí Cee-C.

 

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti