Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni #olowo laimọ wipe ko ri bẹ rara.
#ITUMỌ: Itumọ olowo ni gbogbo eniyan ti asiri ẹ bo, to jẹ pe t’oba fẹ lo owo kan to n ri lo lasiko to yẹ ati asiko to fẹ.
#ẸKỌ: Ẹ ma jẹki a maa fi ọla awọn kan ta o mọ ibiti wọn ti r’owo wọn tọrọ mọ. Ni agbara Ọlọrun, asiri gbogbo wa koni tu, amin!!!