Agongo sígo sígo The Ifa diviner called Agongo sígo sígo Agongo sìgo sìgo Another Ifa diviner called Agongo sìgo sìgo A dífá fún Ògúndá They were the diviners for Ògúndá Èyí tí ó tẹ̀hìn wá The one who came from behind Tó wá borí Ogbè mọ́lẹ̀ And outperformed Ogbè…. Ògún tẹ̀hìnwá o Ògún emerged from behind Ògún borí Ogbè mọ́lẹ̀ And outstripped Ogbè Orí rere ni tìrèère The head of the turtle is a fortunate head. Gboyega Oyetola has now ...