Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán; Toke Makinwa  jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà. 
toke

Àwòrán; Toke Makinwa  jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà. 

Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé.  Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò   pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà tí a mò sí Calvin Klein isé owó Harvellastyles ni, ó wà lójú ònà tí ó ńlo sí TouchHD fún ìfi-òrò-wá ni -lénu -wò lórí redio. Nígbà tí ó jáde pèlú oba ilé-isé redio Tbo Touch.
Toke ti wà ní ìpele tí ó kéyìn ní ìrìnàjò àgbáyé látàrí dídi ògbó-n-tarìgì ònkòwé tí ó ń tèlé àwon ìpele tó tó ní United State, Ghana àti United Kingdom.
Yó ò gba tí to wó bo ìwé àti kíka ìwé ní ojó Àbáméta…..

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

toke

A widow begged Toke Mawinwa money for her Son’s School fees, see her response

This is very kind of her ….read the conversation below