Home / Art / Àṣà Oòduà / Eji Ogbe Verse

Eji Ogbe Verse

Jọ̀gbọ̀dọ̀ lẹ̀fọ́ lorúko ti Ifá ńjẹ́
Ẹ̀rọ̀ wọ̀ loyèe tẹ̀tẹ̀

Ayé kọpá
Ẹ̀sọ̀ lo gbà

Èle tán láye
Ẹ̀rò ló kù

A dífá fún Ìrókò Ẹlujù
Tí wọ́n ní ó máa so okùn
Kó tún máa so oyindẹ

Ìrókò kó o má so èle
Ẹ̀rọ̀ were nÌrókò ń so
Ẹ̀rọ.

Courtesy: Moyo Okedeji

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifa on sex

Ifa on Sex and Sex Positions With Owomide Ifagbenusola