Home / Art / Àṣà Oòduà / O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC

O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC

O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC

Alaga patapata fun eto idibo ni orileede yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo n salaye yii ni ilu Abuja.
O ni pelu rogbodiyan to n lo ni ipinle Edo, awon kan ti n gbee poori enu pe INEC maa fi kun ojo idibo. O ni ko si ohun to joo.


Yakubu ni ojo kokanla osu kesan-an odun yii ni idibo si ipo gomina maa waye ni ipinle naa.

Alaga yii ni gbogbo fifi oruko sowo si ajo INEC naa wa laarin ojo mewaa si asiko yii. O ni o pe ju,aago mefa irole ojo kokandinlogbon osu kefa yii ni iforuko sile naa maa dopin.


Yakubu ro awon egbe oselu meedogun to maa dije du ipo gomina maa ki won tele ofin orileede yii ati ti alaale oselu.


Alaga nii ki won ma se gbagbe nnkan merin to se pataki ki won to foruko asoju nibi idibo abele ranse si ajo oun. O ni oloselu to fe dije du ipo gomina gbodo je omo orileede yii, o gbodo pe omo odun marundinlogoji o kere tan, o gbodo je omo egbe oselu naa, bee si ni eni naa gbodo kawe, o kere tan iwe mewaa.

Mahmood Yakubu nu leyin gbogbo eyi,idibo lo ku ni ojo idibo.

Yínká Àlàbí

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Agodongbo

What is Agodongbo Called in English and Chinese?

Agodongbo is called Colt in English Language and in Chinese it is called Xiǎo mǎ. The term “colt” only describes young male horses and is not to be confused with foal, which is a horse of either sex less than one year of age. Similarly, a yearling is a horse of either sex between the ages of one and two. Agodongbo