Home / Art / Àṣà Oòduà / Oro kan fun odaju abiyamo !

Oro kan fun odaju abiyamo !

Eku ojumo esinku isimi oni,besini esin tun ku oro ilu, hmm awon yoruba ama paalowe wipe eniyo npanu eni ebinpanranku,Ewo omo tuntun jojolo yi nibi ti wonsonu si ninu poli bagi,sugbon osemilanu wipe omo natidagbere faye bayi ni oni paanu leko,awon kan nwa won ori beni awon kan ri wonmolo ,oro kan fun odaju abiyamo.
oro kan fun odaju abiyamo

Benjamin Adekunle

Send Money To Nigeria Free

About admin