Home / Art / Àṣà Oòduà / Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos
Suicide bomber
Suicide bomber

Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos

Bómbù déru bà wón ní ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond bank) ní ìlú Jos, Bí won se fura wípé wón ti wà okò kan gúnlè tí irinsé olóró Bómbù sì wà ní inú rè.  Gbogbo òsìsé ilé-ìfowópamó Diamond ti eka Katako, ní Jos, àti àwon olùgbé ti sí kúrò léyìn tí okò afurasí tí ohun ìjà olóró wà nínú rè wà gúnlè ní iwájú ilé-ìfowópamó náà.
Ilé-isé kan tí a mò sí JTown connect metro kójopò wípé wón ti wa okò náà gúnlè fún ojó kan àti òpò wákàtí séyìn tí enikéni kò sì wá fún un.
Olùgbé àti òsìsé ilé-ìfowópamó ti eka Katako tí èrù ti ń bà pariwo síta or àwon tí ó le gbógun ti Bómbù, won kò sì pé tí won fi dé ibè.
Àwon tí ó ń gbógun ti Bómbù dí ònà tí òpò ènìyàn ń gbà láti dáàbò bo ènìyàn pèlú okò tí ó ń kojá.
Léyìn ìgbà tí won ti se ìwáàdí àti àyèwò fínífíní, àwon olù gbógun ti Bómbù gbógun ti ohun olóró yìí tí ó sì túká yángáyángá. Wo àwòrán síi ní ìsàlè….

English Version
Continue after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti