Home / Art / Àṣà Oòduà / #Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi
iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete.

Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re paaro ti elomiran. Ori kankan to nsise ijoba/adani/okoowo ninu agbole yin yoo ri oju rere Olodumare. Eoni ri ibinu omi, eoni ri ibinu ina, eoni ri ija aye pelu. Oseyi konii dio mon eru lo. Bio se ti bere ojo oni pelu ayo, ayona ni waaafi laaja. Afefe kiife koma kan igi oko lara, abamoda kiida tie k’omase, gbogbo iwure timose fun o ati agbole re lowuro yi a kanyin lara lase Edumare. Bee ni yori funmi ati idile mi niyen…Ire ati Alaafia.

Iwure yi wa lati enu Ojise Olodumare, High Chief Kolawole Ifarotimi. FCT, FTFN, FCB.

Ejubona Ilara Remo,

Babalaje Onisango Remo Land,

Asiwaju Elebo Worldwide.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti