Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.

Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.

Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti gbìyànjú àwon nkan tí mò ti kà ní orí èro ayélujàra Kódà a tún jo lo sí ibi àpérò láti le jé kí ó yí padà sùgbón kò yí padà… E jò wó mi ò so eléyìí láti bà á jé sùgbón ònà yí nìkan ni mo gbèrò kí ó yí padà .

Egbàmí n’ímòràn e jò ó!!!

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti