Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je. Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo to wa niluu Eko lagbo wi pe o bere ise fiimu agbelewo lodun 2006. Omo bibi ilu Edo ni sugbon ede Yoruba eni re da saka.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


