Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro Olorun ti okiki re kan kari aye ni, bakan naa lo tun je oludasile ile iwe. A ba olojo ibi yo lonii, a si gbadura wi pe Olorun yoo so agbara Bisoobu dotun. Igba odun, o dun kan ni.
Source: olayemioniroyin.com