Home / Art / Àṣà Oòduà / Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri: Jenifa Pe Omo odun Mejidinlogoji (38)
funke

Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri: Jenifa Pe Omo odun Mejidinlogoji (38)


Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! Lati irun ori re de bata to wo sese ni i sana bi ti ina elentiriki.

Aso kaba to wo tun leku! Aso naa kii se tile yii, toke okun ni. Aso ti won fi goolu ati owu dudu ran pelu bata onile gogoro lese.

Aso naa o de orunkun re; ilaji itan lode. Eleyii to fi anfaani sile lati ri ilaji itan ese re nita. Itan omoge naa tutu loju bi edo eran ti won ko jade lati inu omi bee lo mo lolo lailabawon bi ara omo tuntun jojolo.

Yato si eyi, aso oge re tun rora si igbaaya re sile ferefe, eleyii to je wi pe ko si okunrin ti o gboju sona ibe ti ko tun ni fe tun wo leekan si.

Atike oju re ko poju, iwonba naa si tun ni itote pupa enu re.

Eniyan dudu ni Funke sugbon o dabi eni wi pe oju re ti n funfun.

Odun 1977 ni won bi Olufunke Ayotunde Akindele si agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko.
Ojo aje to koja yii lo si pe omo odun mejidinlogoji (38).

A ki Jenifa wi pe oku ori ire. Igba odun, odun kan ni

Source

About Lolade

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria