Olúbámbí, Àfọ̀njá, Ewélérè
Ọba a Kòso
Àtijẹ, àtimu, ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀
Ẹ mọ́ safẹfẹ yẹ̀yẹ̀ sí wa mọ́
Afẹfẹ yẹ̀yẹ̀
Ewé ọdán ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ
Ẹran ló fi jẹ
Afẹfẹ yẹ̀yẹ̀
Olúbámbí, also hailed as Àfọ̀njá, Ewélérè
King of Koso
To eat and to drink, are separate matters
Stop your vanity ways with us
Vanity, sheer vanity
The ọdán leaf tried vanity with us
And a goat ate it up.
Vanity, sheer vanity.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


ok
ok
ok
ok
ok
Seen
Seen
Seen
Seen
Seen