Home / Art / Àṣà Oòduà / Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin

Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin


Honorebu Suleiman A. Kawu ni yii, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ti n fo iganna nigba rogbodiyan to waye nile igbimo asofin ni akoko ti Goodluck Jonathan wa lori oye gege bi Aare ile Nigeria olominira.

Maanu yii kan naa wa lara awon ti Aare Muhammadu Buhari ti yan bayii gege bi oludamoran nipa awon oro to n lo nile igbimo asoju sofin ile Nigeria.

Pelu bi oko Aisha se n pariwo wi pe awon eniyan gidi, omoluabi oloselu ati olooto ni awon eniyan ti oun fe ninu isejoba oun, nje awa le pe eniyan ti n fo iganna gege bi omoluabi alaponle bi?

 

Orisun

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

olodumare

The True meaning of Olódùmarè (Olodumare) – By late Prof. Sophie Oluwole

Olodumare – Oni Odu Mare- Eni ti O ni Odu ti ko kin re. Olódùmarè is Olodumare and there is no English word or translation for Olódùmarè. The English Language (The culture of the colonial master) is fund of applying different rules to comparable situations, for the simple reason Olodumare cannot be equal to the small letter g or capital letter g defamation of the Olodoumare. Olódùmarè is also not a lesser god or God. Olódùmarè is simply Olodumare. Olódùmarè ...