His Imperial Majesty, Alaiyeluwa Oba Ajibade Gbadegesin Ogunoye III, The Olowo of Owo and Paramount Ruler of Owo Kingdom
Picture: Igogo festival 2019
See more photos bellow
Omooba obinrin kan gbe ni ilu alayo, orewa pupo ju oruko re si nje Amoke ni ile Yoruba atijo. Orewa pupo debi pe gbogbo okunrin ilualayo niwon ko enu ife si, koda awon okunrin ilu agbegbe won gan o gbeyin. Amoke n ma bu gbogbo awon okunrin ti oba soro ife leti re koda atun pariwo lewon lori. Oro yin kan Oba ilu ti oje baba re lomi nu. Loru ojo kan, Oba ji Amoke sile o de ba so ...