Ile Ife – Ọọni
Ileṣa – Ọwa Obokun
Ila – Ọrangun
Osogbo – Ataọja
Ẹdẹ – Timi
Iwo – Oluwo
Ejigbo – Ogiyan
Iragbiji – Aragbiji
Oba – Ọlọba
Ikire – Akire
Imesi ile – Ọwa ooye
Ife odan – Adimula
Ipetumodu – Apetumodu
Iloko – Aloko
Modakeke – Ogunṣuwa
Ikirun – Akirun
Ilobu – Olobu
Orile owu – Olowu
Erin Ijesha – Akinla
Apomu – Alapọmu
Esa oke – Ọwa omiran
Iree – Aree
Ile ogbo – Olu
Ijebujesha – Elegboro
Ọtan ile – Ọlọtan
Ifewara – Olufewara (Adimula)
Ifon – Olufon
Okuku – Olokuku
Masifa – Ọlaaresa
Ijabe – Onijabe
Ekosin – Akosin
Igbajo – Ọwa
Edunabon – Salu
Kuta – Olowu
Iragberi – Aragberi
Ifetedo – Olubosin
Iresi – Olúrèsì ti Ilú Iresi
Ora igbomina – Asaoni, Akesin
Ogbaagba – Agbowu
Okua – Olokua
Eko ende – Ẹlẹndẹ
Ada – Ọlọna
Ipetu Ijesha – Ajalaye
Ikeji ile – Arakeji
Ayepe olode – Olu
Gbongan – Olufi
Oshu – Oloṣu
Otan ayegbaju – Ọwa
Oke ila – Ọrangun
Ikoyi – Olukoyi
Ibokun – Ọwa
Okinni – Ọlọkinni
Inisa – Oluniṣa
Ode omu – Alayegun
Iperindo – Tirimi
Oyan – Ọlọyan
Sekona – Olu
Ibodi – Ọlọja.