Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...
Read More »Fidel vs Awolowo
That’s why in the history of Yoruba and Nigeria. We haven’t be able to produce toothpick to export to U.K. . Do not fool yourself. Nigerian leaders in 1960 were puppet of the British. At least, you all know about ...
Read More »Nesse Osé Obaluwaye
Que nesse Ose Obaluwaye, todas as dificuldades se vão pra bem longe de nossa família. Peço que divindade que coroou todos os Orisas em cima da Terra, traga reconhecimento e respeito ao nosso Ori. Que a Terra sempre nos seja ...
Read More »256 Odù Ifá signatures !
ÈJÌÒGBÈ I will be posting the 256 Odù Ifá signatures over the next one year. ( Bookmark this page or save it as it will be updated everyday/week) If members are so inclined, they are encouraged to add Ẹsẹ Ifá ...
Read More »Ifa olokun adore dayo aso oro gbogbo wa di ayo ooo.
Ase !
Read More »Ìká Méjì No 11.
Ifa foresee lot of Ire for the person this Odu is revealed to. He/she need to offer Ebo so that Ase can be in his/her mouth. Ifa said if this Odu was revealed to a woman that is unable to ...
Read More »Can anyone stop the river from flowing?
If the answer is no, then nobody can stop Elerii Ipin from delivering miracles. Listen to this sacred message of Olodumare from Ogbe bara as follows :- Ogbe gbarada tan telegan loku Ifa seun gbogbo tan o ku telenu Adifa ...
Read More »Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...
Read More »Isebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a
ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
Read More »Ose tu’a
ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...
Read More »