Home / Author Archives: ayangalu (page 110)

Author Archives: ayangalu

Ogbe Rikusa ifa Divination

What is Ose Ifa ?

Ose Ifa is like Thanksgiving. You do it for additional blessing. Please listen to this from Irosun Awoye(Irosun Iwori) Finfin ni tigba Ira ni tagbe Adifa won ni Awoye. Ti won joye alaimoore Erigi alo, Ifa mo wa yin o ...

Read More »
Iyanifa of iraye remo

Photo of the day – Aboruboye o, Iyanifa!

Iyanifa. of iraye remo  

Read More »
ebo yoruba

“I’ve done several ebos (sacrifice) but my situation financially is getting worst”…

A friend, not yet a fully fledged Babalawo, called me from Venezuela and said as follows:- “Araba, my friend, I think I am going to throw Orunmila away(he meant Ifa)”.I asked, why? He said, “I have done several ebos(sacrifice) and ...

Read More »
Òkànràn meji

Òkànràn Méjì ‘NO 8’.

In this Odu, this person needs to reduce his/her level of anger for Ire to stay with him/her. This person needs to know that, he/she is affiliated to Sàngó, therefore he/she needs to always feed Sàngó every time for victory ...

Read More »
Ori

Oriki Ori…

Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...

Read More »
olodumare

If you don’t believe in “what will be will be”, then listen to voice of Olodumare in “Idin Ileke (Odi irete)”

A baa wo ‘yara ka ti’lekun mo ‘ri Ohun ti o ma se ni ko ni sai se ni Adifa fun Orisanla Oseremogbo Ti ntorun bo wa’ye Won ni bi o ru’bo nkan nla kan o se Won ni bi ...

Read More »
ewe karaleye

Kereyale / Yale – Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi

  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa sire gbogbo, bi odun yi se ntan lo akoni fi aisan pari re lase eledumare ase. Laaro yi mo fe ki a mo iwulo ewe ...

Read More »
ase

Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….

Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...

Read More »
odo iwoyi

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb