*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Iwure Owuro – 14.03.2016
*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwa Dabi Eyin
Toju iwa re iwo ore mi. Maa ranti wipe iwa-lewa. Ewa bii iwa ko si. Bi o ba dara bii egbin. Ti o tun rewa bi okin. Eran ikan ni lojo tiku ba de. Sugbon iwa lohun ti kii ku. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Owe Toni: Pari owe yi
1.Awolu mate e????? 2.Enitio dasofun ni??????
Read More »ayangalu Comments Off on GBEJÉÉ KIO NIYI
Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké, ...
Read More »ayangalu Comments Off on ibere ranpe daruko awon nkan meji yi ati wipe awon wo ni won nlo ?
jowo fi idahun re sowo si mi ti o ba je ojulowo omo yoruba
Read More »ayangalu Comments Off on Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji
Awon Yooba bo, won ni owo tada mo ni kada lehin. Iku ogun ni i pa akikanju, omi ni pada wa pa omuwe lodo. Okan ninu awon omo asewo ilu Abuja ti oruko re n je Omidan Ome Enyi lo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Femi Adebayo, Funke Akindele, Mercy Aigbe, Toyin Aimakhu nibi ami eye Africa Magiki 2016
Aimoye osere lo peju sibi ami eye (Africa Magic Viewers Choice Awards) 2016 to waye niluu Eko. Eyi to waye yii ni i se elekerin iru e. Oruko awon olubori ami eye naa wa nisale .
Read More »ayangalu Comments Off on Won ti pago lori maanu to fowo kan oyan omoge
Arabirin, Ifeoma Okoroafor, eni odun mejidinlogbon (28), lo ti salaye fun ilejo Upper Area Court to wa niluu Abuja wi pe, Ogbeni Musa Goddy fowo gbe oun loyan jo ni oun se fo nigo lori. Ogbeni Musa lo fejosun lago ...
Read More »ayangalu Comments Off on Owo Jegudujera Abacha: Ile ejo ti fesun kan Obasanjo ati Jonathan
*Won tun ranse si Yar’Adua lode orun wi pe ko wa salaye *Ile ejo ti gbe ise to le fun Aare Buhari lati se Obasanjo, Yar’dua ati Jonathan Kootu ijoba apapo to gaju lo to kale siluu Eko, Federal High ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Awon soja yin mi ni bajinatu, won fe pami” – Olu Falae
*Awon ika eniyan wo lo wa nidi isele yii? *Se agbanipa ni won tabi awon soja ti won se palapala nigboro? Oloye Olu Falae ni ori ti koyo bayii lowo iku ojiji nigba ti awon soja kan ti enikeni ko ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more