Today’s Oodua words
Read More »
ayangalu Comments Off on Oodua words for today
Today’s Oodua words
Read More »ayangalu Comments Off on Video: Egungun festival
ayangalu Comments Off on Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn
Adífáfún ifátérú tí se omokùnrin ìgódó,Èdùmàrè àwa yìn ó kí o tún le se òmírán.?????I give thanks to Elédùmarè, for everything he has done for me, orí modupe, Ifa modupe, Egbe aye ati t’òrun modupe lowo yin.?????? Thanks to everyone ...
Read More »ayangalu Comments Off on APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan
APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan Láìpẹ́ yìí ni ìròyìn kàn pé ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC) tó ń ṣe àyẹ̀wò àwọn olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ náà sọ pé Segun Abraham ni kò ...
Read More »ayangalu Comments Off on Wọ́n gbẹ̀mí olórí ẹgbẹ́ jàǹdùkú ”One Million Boys” n’Ìbàdàn
Wọ́n gbẹ̀mí olórí ẹgbẹ́ jàǹdùkú ”One Million Boys” n’Ìbàdàn Ọmọ ò fìgbàkan láyọ̀lé, ẹni ọmọ dúró sin onítọ̀ùn ló bímọ. Gbogbo ẹni tó bá bí jàǹdùkú, olè, gbàjùẹ, kọ̀lọ̀rànsí l’ọ́mọ, kónítọ̀ùn ó má tíì yọ̀ láyọ̀jù nítorí pé *ÀBÍKÚ ÀGBÀ* ...
Read More »ayangalu Comments Off on Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩
Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩ Yorùbá bò̩, wó̩n ní ‘àrà ò kì ń tán nínú alárà nígbà kankan’. Gbajugbaja Semeyo Dino Melaye tí gbogbo ènìyàn mò̩ bí e̩ní mo̩ owó tún gbé àwo orin jáde nípa olórí àjo̩ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu
Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu Gomina ipinle Eko,Alagba Babajide Sanwo-olu lo n salaye yii fun awon alase ati awon akekoo ile-iwe Corona ni ilu Eko.O ni o se oun laanu pe bi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọbásanjọ́ tìkẹ̀kùn mọ́ àwọn òṣìṣẹ́, ojúlùmọ̀ níbi òkú àna rẹ̀
Ọbásanjọ́ tìkẹ̀kùn mọ́ àwọn òṣìṣẹ́, ojúlùmọ̀ níbi òkú àna rẹ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, bí ìṣẹ̀lẹ̀ bá sẹ̀ ní agboolé, a mọ́ ọ kángun sẹ́nìkan ju ẹnìkan lọ.Ọ̀rọ̀ rí bẹ́ẹ̀, nígbà tí Àárẹ̀ tẹ́lẹ̀rí lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olusegun Obasanjo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọjọ́ Kẹrin oṣu Kẹ́jọ ni ìdánwò WAEC yóò bẹ̀rẹ̀ – Mínísítà ètò ẹ̀kọ́
Ọjọ́ Kẹrin oṣu Kẹ́jọ ni ìdánwò WAEC yóò bẹ̀rẹ̀ – Mínísítà ètò ẹ̀kọ́ Ìjọba àpapọ̀ ti kéde pé ìdánwò àṣeparí ní iléèwé girama, WAEC, yóó bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrin oṣù Kẹjọ ọdúnMínísítà ètò ẹ̀kọ́, Emeka Nwajiuba ló fi ọ̀rọ̀ náà léde ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey
Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey Ó dà bí ẹni pé àwọn èèyàn kìí fẹ́ rán aṣọ wọn níbi tó gbé ya mọ́ lóde òní. Ìtọ pinpin àti àríwísí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀ ló kù tí wọ́n ń mójútó, bọ̀kílẹ̀ èyí ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more