Home / Author Archives: ayangalu (page 36)

Author Archives: ayangalu

corona

Adarí àgbà ilé ìwòsàn UCH kò ní àrùn Coronavirus mọ́

Họ́wùú! bí babaláwo bá ń kígbe ẹ̀fọ́rí, kín ni yóó jẹ́ àtubọtán aláìsàn? Kò jẹ́ jẹ́ bẹ́ẹ̀. Adarí àgbà ilé ìwòsàn ẹ̀kọ́ṣẹ́, UCH Íbàdàn Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Otegbayo ti yiijẹ o, kò ní àrùn Coronavirus mọ́ lẹ́yìn tó sàyẹ̀wò àrùn náà ...

Read More »
court

Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà

Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode. Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ...

Read More »
Seyi Makinde

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19

Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni ...

Read More »
fg

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’EkooÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won ni alaare ko ki n ...

Read More »
coronavirus

Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria

Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní NaijiriaÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Eniyan ogun lo tun kun awon ti arun coronavirus n ba ja ni orileede yii ni oni ogbon ojo, osu keta odun 2020.Metala ni Eko, merin ni ...

Read More »
seyi makinde

Ṣèyí Mákindé, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìpàdé ètò ọrọ̀ aje Nàìjíríà l’òun ti kó àrùn COVID-19

Ṣèyí Mákindé, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìpàdé ètò ọrọ̀ aje Nàìjíríà l’òun ti kó àrùn COVID-19

Read More »
Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Nílẹ̀ Amerika Ti Ju Ti Italy Àti China Lọ!

Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Nílẹ̀ Amerika Ti Ju Ti Italy Àti China Lọ!

Ìlẹ̀ Amẹ́ríkà mà ti gba ipò kínní gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè tí ìtànkálẹ̀ Coronavirus ti pọ̀jù lọ l’ágbàáyé pẹ̀lú ènìyàn tó lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà márùndínláádọ́rún tó ti ní àrùn náà.

Read More »
coronavirus

Ojúmọ́ Kan, Oògùn Kan

Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko ...

Read More »
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan si n yo ijoba ipinle Eko lenu pe ki o ti gbogbo ilu pa lo le segun arun naa daadaa. Sanwo-Olu da won lohun pe arun naa ko ti ran de iye to le mu ki ijoba ti gbogbo Eko nitori ipo ti ipinle naa wa ni orileede yii. Gomina Sanwo-Olu tun salaye awon to maa letoo si ounje ofe. O ni awon ti eya ara pe nija ati awon arugbo ni eto naa koko wa fun bayii. O ni bi agbara ba se n de sii ni o maa so bi awon se maa te siwaju nipa iranlowo naa. Bayii eniyan aadorin (70) lo ti ko arun buruku naa ti merinlelogoji (44) si sele ni ipinle Eko. Ki Eledua ba wa segun ajakale arun naa.

Sanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan ...

Read More »
Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!

Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!

Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo.

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb