Ààrẹ Donald Trump ń tú bí ejò ní o , pé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ti sọnù látàrí pé China sahun òótọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ tí àlejò ọ̀ran náà tí fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣé bùba , kó tó wá di àǹkóò ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ikú ṣẹlẹ̀ nítorí àṣìṣe àti irọ́ tí China pa lórí coronavirus- Donald Trump
Ààrẹ Donald Trump ń tú bí ejò ní o , pé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ti sọnù látàrí pé China sahun òótọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ tí àlejò ọ̀ran náà tí fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣé bùba , kó tó wá di àǹkóò ...
Read More »ayangalu Comments Off on Olò̩tè̩ èmi àti Aláàfin máa fojú ba ilé-e̩jó̩ – Wasiu Ayinde
Gbajugbaja olorin fuji ti ina orin re si n jo lowo bayii ni o ti fa ibinu yo nigba ti won fesun kan an pe, o ni asepo pelu okan ninu awon olori Alaafin ti ilu Oya, Oba Lamide Adeyemi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Maryam Sanda ṣì wà lẹ́wọ̀n, Buhari kò dáa sílẹ̀.
Iléeṣẹ́ Ààrẹ ló sọ pé Ìròyìn tó ń jà rànyìnrànyìn kiri pé Ààrẹ Muhammadu Buhari tí darí jin arábìnrin náà kìí ṣe òtítọ́ rárá.Ki àwọn èèyàn kọtí ọ̀gbọin sí i.Ní oṣù kínní ọdún yìí ni ilé ẹjọ́ dá arábìnrin Maryam ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Saudi Arabia ti fòfin de kíkí ìrun Asham ní àwọn mọ́sálásí tó wà níbẹ̀
Àwọn aláṣẹ Saudi sọ pé kò ní ín sí ìrun Asham tàbí Taraweeh, ní àwọn mọ́sálásí tó wà ní ìlú Makkah àti Medina, àyàfi tí àrùn apinni léèmí coronavirus bá ti káṣẹ̀ nílẹ̀. Mínísita fún ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn lórílẹ̀-èdè náà, Abdullateef ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello
Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri. O ni loooto ni adari aabo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo
Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa books at affordable prices (now in stock)
ifa books
Read More »ayangalu Comments Off on In Loving Memory Of Prof. Akinwunmi Ishola
Professor Akinwunmi Isola was a Nigerian playwright, actor, dramatist, culture activist and scholar. He is known for his writing in and his work in promoting the Yoruba language. Books: Efúnṣetán Aníwúra, Iyálóde Ìbàdàn, and Tinúubú, Ìyálóde Ẹgbá, Madam Tinubu, MORE Prof. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Happy Ose Ifa to all Ifa devotees globally.
Happy Ose Ifa. An Odu references all situations, circumstances, actions and consequences in life, based on the innumerable ese (poetic tutorials/recitations) relative to the 256 Odu coding. In other words an Odu is your life path. Each Odu has over ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé
Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé Fẹ́mi Akínṣọlá Oríṣìríṣi ìjìyà ni ìjọba orílẹ̀-èdè India ti gbà nípaṣẹ̀ àwọn agbófinró láti máa jẹ àwọn kọ̀lọ̀rànsí tí kò bọ̀wọ̀ fún òfin kónílé-ó-gbélé ní ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more