Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...
Read More »The Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria – Photos
Bellow is the photo of Elemoso Ogun of Ijagbo Land and Oluode Aluwo Of Offa at the Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria. See another photo bellow
Read More »Annual Ifa Festival: Save the date!
Please sing along with me as follows:- Mi o fi sawada mo wi o, mi o fi sawada Bi mo t’ayewa onifa ni N o seMi o fi sawada mo wi o This is not a joke, I declare, I am ...
Read More »Ori mi Apeere
Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si Orisha ti danni gbe leyin ori eniOri ...
Read More »Ẹyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko
Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa ...
Read More »Odu Ifa,”Irosun Oyeku” Cast Today For Ose Ifa
Looking at Odu Ifa, “Irosun Oyeku” cast today for Ose Ifa, I can advise all Priests and Priestesses to imbibe calmness in their characters so that they can always achieve their desires. Secondly, the stanza contains one of the Yoruba ...
Read More »Odu “Ose di” cast for today’s Ose Ifa,
Looking at the Odu, “Ose di” cast for today’s Ose Ifa, I can boldly say that we possess the treasure of inestimable value. Just listen:- Sarasara ni won ndafa awoWoyowoyo laa dafa ogberiAdifa fun Orunmila baba yoo fi Wura sobinrinAwo ...
Read More »Ayoka: The Daughter Of Iya Oniworobo Omo baba Elemun Ni Sabo
It been a long time coming But still, I ignored all your forming Have been to the moon and backJust to cater for all that you lack Don’t you realize that you’ve been single for a while ?Have been chasing away ...
Read More »Ifá naa ki bayi wípé…
Ifá gba gbogbo akápò re niyanju wípé ki won o rubo nitori ki a baa le ri orí ayé wa, ki a baa le de ile ileri, ifá ni nkan yio soro tabi le die fun awon ti won ba ...
Read More »Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !
Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. ...
Read More »