*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Akara Imora’n toni – 09.07.2016
*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk
Read More »Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...
Read More »ayangalu Comments Off on Tani Onife Si Julo Ninu Awon Osere Meji Yi ?
ayangalu Comments Off on Orunmila o jiire loni oooooo!
Oluwo Agbaye; Olori Awo Ode Isalaye; Ifa a mo oni mo ola bi Oba Olodumare; Igba eran ni a fi i bo’Fa; Aboruboye! Aboyeboru! Aboyebosise! cc- Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole
Read More »ayangalu Comments Off on Idile Alayo – Odun ikerin ree ti mo ti se igbeyawo sugbon…
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewu Gereye – Adeyanju Ahmed Akewi Imoran
Iya nii je ta ni moo ri, Owo tabua nii je mo ba o tan Igba taa ba n wo sokoto penpe Baye ba ko ni lona Won le moju fira bi eni ofo se Boo rokele atata bu Aye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Osu Tuntun 01.07.2016
E MAA WI TELE MI : ………… *Osu yii, osu aseyori mi ni. *Osu iserere mi ni lase Edumare. *Osu igbega mi ni. *Osu idunnu mi ni. *Owo a fi ilee mi se ibugbe. *Akoba, adaba ko ni je temi. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ogulutu Oro Toni – 30.06.2016
Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se tomuje ,kehinde lese koyi lowo.. Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo King Ogulutu Oro
Read More »ayangalu Comments Off on Ibeere Toni
Nje oda ki Ololufe Meji jo so bi won se gbe igbe aiye won kiwon to pade arawon paapa julo obinrin????
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more