Home / Art / Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

baale esu

Meet the Baale Esu of Osogbo Oloye Kayode Idowu Esuleke as He Explains who Orisha Esu is |Who is Esu

Read More »
Àwọ̀ ni Édè Yorùbá

Àwọ̀ ni Édè Yorùbá – Colours in Yoruba Language

Dúdú – BlackÀwọ̀ Ojú Ọ̀run – BlueÀwọ̀ igi – BrownÀwọ̀ Eérú – GrayÀwọ̀ Ewé – GreenÀwọ̀ Òféfèé – OrangePupa – RedFunfun – WhitePupa rusurusu – YellowÀwọ̀ dúdú – Dark colorLight color: Àwọ̀ tí ó mọ́lẹ̀Colors: Àwọn àwọ̀  Ojú Ọ̀run dúdú díẹ̀ – ...

Read More »
Ikán parapọ̀, ikán mọ ilé; èèrùn parapọ̀, wọ́n mọ àgìyàn; àwọn oyin parapọ̀, wọ́n mọ afárá.

Òwe Tòní

Ikán parapọ̀, ikán mọ ilé; èèrùn parapọ̀, wọ́n mọ àgìyàn; àwọn oyin parapọ̀, wọ́n mọ afárá. TranslationThrough collective labour, termites erected majestic cities, ants built fortified strongholds, and bees fashioned efficient honeycombs. WisdomUnity is strength, and together, we achieve more! ...

Read More »
Òwe Tòní

Òwe Tòní

Apọnkọ kéré ò gbọn to asọwò márà, ọgbọn asọwò márà kò tó ti ajéáwọgba, ọgbọn ajéáwọgba kò tó ti Ìyá mi ò ran mi lẹkọ̀. The person who sells a short measure of pap is not as smart as the ...

Read More »
ipinle eko

Awọn Olùgbé Ìpínlè Èkó Pè Fún Ìpàdé, Bí Ìjọba Ìpínlẹ̀ ÈKó Ṣe Sí Atẹ Ètò Tuntun Tí Wọn Lè Gbà Sọrọ

Àwọn Olùgbé Ìpínlè Èkó pè fún Apero, bí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ṣètò àwọn Nọmba ẹrọ ibanisọrọ mẹta t’awọn aráàlú lè pe sí tí wọn yóò tún bá àwọn oṣiṣẹ Ọba sọrọ.Àwọn Nọmba ẹrọ ibanisọrọ métèèta jẹ tí Ilé -Ise ...

Read More »
OBARA-OSE OBARA

OBARA-OSE: OBARA

Eni ise nse Eni iya n je Obara pe legan o dowo loko. Obara pe lajo o dolowo. Obara pe lajuba o pada wa la . O donipepe ajiki ; O di ori aji filu pe.OSE seran seran o ni ...

Read More »
masoyinbo

#Masoyinbo Episode Twenty-Seven: Exciting Game Show Teaching Yoruba Language & Culture!

Read More »
isese

ÌṢẸ̀ṢE Calendar For The Month Of June, 2024

01. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀. 02. Ṣàngó/Jàkúta, Ọya, Baáyànnì, Aganjú, Ọbalúayé/Ṣànpọ̀nná, Nàná-Bùkúù. 03. Ọbàtálá/Òrìṣà-Ńlá, Yemòó, Èṣù, Egúngún, Ẹgbẹ́-Ọ̀gbà/Alárá-Igbó, Orò, Ẹ̀lúkú, Agẹmọ, Òrìṣà-Òkè, Ògìyán/Ògìrììyán. 04. Ifá/Ọ̀rúnmìlà, Ọ̀ṣun, Ọ̀sanyìn, Yemọja, Olókun, Ẹ̀là. 05. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Òrìṣà-Oko, Erinlẹ̀. 06. Șàngó/Jàkúta, Ọya, ...

Read More »
taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete

Read More »

Understanding Ẹdan Ògbóni

Ògbóni; ÒgbórànErelú; ÀbíyèEríwo yà!; À yà gbó, À yà tó! The old ones; Increase with age. Titled female elders; May children be born to liveThe Lord of secrets, descend!; For longevity and prosperity! Ẹdan Ògbóni is a pair of male ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb