orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon
orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu ...
Read More »ayangalu Comments Off on E Ase iwure yi ooo
Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…
eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Read More »ayangalu Comments Off on Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »ayangalu Comments Off on Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira
Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibeere Toni: 15.05.2016
Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Read More »ayangalu Comments Off on Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Owuro: 14-05-2016
E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...
Read More »ayangalu Comments Off on Aku ojumo lokun !
Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more