Adifafun perengede Tinseyeye Ojumomo, Ojumotomo wa loni Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa Perengede Iwo ni yeye Ojumomo Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa……. ASHEE ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on “OPELE loyo tan to dakun dele
Adifafun perengede Tinseyeye Ojumomo, Ojumotomo wa loni Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa Perengede Iwo ni yeye Ojumomo Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa……. ASHEE ...
Read More »ayangalu Comments Off on Orewa kilode kilo fa ironu?
Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro ...
Read More »ayangalu Comments Off on Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »ayangalu Comments Off on Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oba Erediauwa Ti Waja
Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »admin Comments Off on Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)
E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »Lolade Comments Off on Aderupoko lori Eto Gbajumo Osere
Lolade Comments Off on Bobo B lori Eto Gbajumo Osere
admin Comments Off on YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ
A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »admin Comments Off on Olojo Ibi
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more