Awon Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pese ohun ti awon omo won ba n fe nikan, bikose lati sakiyesi iru ebun ti ...
Read More »Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...
Read More »Foto: Saheed Osupa Mr Designer
Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile ...
Read More »Fila o dun bi ka moo de…
Oni fila yii
Read More »Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna
1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...
Read More »O di gbere! Abubarka Audu wole sun
O ku die ko je gomina niku mu lo. Igba ti okiki re bere si ni i kan, lo wole sun. Ojo ti idile re i ba fo fayo, ni won bo sinu ibanuje nla. Ile aye asan, ile aye ...
Read More »Kini yoo sele si orekelewa aya Abubarka Audu?
Omodebirin yii ni okan ninu awon iyawo tuntun ti Abubarka Audu ko sile to fi n sararindin nigba aye re. Gege bi ohun ti Olayemi Oniroyin gbo, ojo ori omobirin naa ko le ju bi odun mejidinlogun (18) si ogun ...
Read More »Awon foto lati ibi eto isinku Abubarka Audu nipinle Kogi
Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.
Read More »Aworan Bukola Saraki nibi ayeye odun SilverBird
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, wa lara awon alejo pataki ti won peju sibi ayeye odun marunlelogbon (35) ti won ti da ile ise SilverBird sile. Minisita fun eto iroyin, Oloye Lai Mohammed naa wa nibe lati soju ...
Read More »Asake pade Lagidigba niluu London
Laipe yii ni Feyikemi Niyi-Olayinka, okan ninu awon sorosoro ori telifisan, dagbere irin-ajo re siluu London. Aworan re ni yii pelu okan lara awon osere tiata Nollywood, Sola Sobowale, niluu London. Lara awon fiimu olokiki ti Sola Sobowale se ni fiimu Lagidigba, ...
Read More »