Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...
Read More »ayangalu Comments Off on Eyelé kìí léegun ìsé lára …
Eyelé kìí rìnrìn ìyà l’ésè Eye tó bá ye làá pè l’éyelé. Good morning Universe!!! May the blessing of today abide with each and everyone of us. Ase!!! Popoola Owomide Ifagbenusola
Read More »ayangalu Comments Off on Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm erora gbogbo yan ale yan ale Nje O mo wipe ohunti ntan lodun eegungun bi? Woo Orewa Kosi nkan towa nta ju ohun towa nile lo bi Iwo naa ba toju titie dada yio rewa yio wuyi loju Gbomi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Awon ona wo ni a le gba lati gba ara wa si ‘le ni oko eru paapa ni owo awon oyinbo ati arabu?
English: What are the ways to free ourselves from the physical, mental and spiritual enslavement especially from the hands of Europeans and Arabs? Cc – Omo Oba
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Eji Ogbe
Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ará Ọ̀run
Cc – Moyo Okediji
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa naa ki bayi wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, eledumare yio saanu wa o ao ri tiwa se loni, iyan jija koni ranwa lo sibiti ako fe o ase. Odu ifa ogbeweyin ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odo Iwoyi: Oro Kan Ni Nrumi Loju Ti Mo Si Nilo Amoran Lori Re.
E ku ile ni a n k’ara ile, e ku abo ni a n k’ero ona, ti a ba ti rira eni tipe, e ku atijo ni a ma nki ara eni. Mo ki gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa Toni Ki Bayi Wipe
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase. Ifa toni ki bayi wipe: Orunmila ni ori a lana kan Moni ori a lana kan ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more