Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908
Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to ...
Read More »Ifá is a system of divination that originated in West Africa among the Yoruba ethnic groups. It is also practiced among believers in Lucumi, (sometimes referred to as Santería), Candomblé, West African & Diaspora, and similarly transplanted Orisa’Ifa lineages in ...
Read More »admin Comments Off on Yunifasiti ijo Mountain of Fire yoo bere eko kiko lojo Monde
Gbogbo eto ti to bayii fun ileewe giga ti ijo Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) eleyii ti won pe ni Mountain Top University lati bere eko kiko fun awon akekoo lojo Monde ose yii, 21/12/15. Eto ibere eko ...
Read More »admin Comments Off on E Sora! FRSC ti kede oju ona to lewu n’Ijebu
Orisun iwe Iroyin: Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon eso oju ona ile Nigeria, Federal Road Safety Commission (FRSC), eka ti Ijebu Ode ti kede awon oju ona to lewu ni gbigba fun awon onimoto ni akoko poposinsin odun yii. Oju ...
Read More »admin Comments Off on Nipinle Ondo, awon osise ko rowo osu gba lati sodun Keresimeis
*Ijoba da awon osise 62 duro lenu ise Orisun: Olayemioniroyin.com Nibayii, Trade Union Congress (TUC) eka ti ipinle Ondo ti n ro gomina ipinle naa, Olusegun Mimiko, lati san awon owo osise ti won je seyin ati awon ajemonu won ...
Read More »admin Comments Off on Oselu Kogi: “Idi ti a ko fi yan Faleke ni yii” – Alaga APC
Alaga fun egbe oselu APC lapapo, Oloye John Odigie-Oyegun ti salaye idi pataki ti awon agba egbe naa fi pamopo lati yan Alhaji Yahaya Bello gege bi oludije ti yoo ropo Abubakar Audu, eni to jade laye saaju ki eto ...
Read More »admin Comments Off on Nipinle Ondo, eniyan meji koja sorun nibi ija NURTW
O kere tan awon eniyan bi meji ni won gborun lo ni Ikare-Akoko to wa ni ipinle Ondo nigba ti awon eniyan bi mewaa farapa koja bikiafu nibi ija to wayii laaarin awon omo onimoto. Wahala to bere lati ...
Read More »admin Comments Off on Emi ati Alao-Akala ti lepo di okan soso- Gomina Ajimobi
*Ajimobi fogbon juko oro si Ladoja Leyin awuyewuye ati awon oro ti n lo nigboro nipa wi pe gomina tele fun ipinle Oyo, Christopher Alao-Akala n mura lati darapo mo egbe APC ti pada jade lenu Akala funra re bayii. ...
Read More »admin Comments Off on “Ko saaye fun Toll-Gate bayii” – Egbe Akoroyin tiluu Eko
E gbe akoroyin, Nigeria Union of Journalists eka ti ilu Eko, ti gbe atejade kan jade eleyii to n ro ijoba apapo lati se atunse si awon oju ona masose wa ki won to ronu a ti da Toll Gate ...
Read More »Lolade Comments Off on Aina Gold lori eto GbajumoTV
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more