Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London. Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on London, e ku amojuba Omo Baba Olowo
Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London. Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?
Read More »admin Comments Off on Ojo ibi Fayose: E wo ohun ti awon tisa fi da lola
Gomina Ayodele Fayose se ayeye ojo ibi odun marunlelaadota (55) lonii ni Ipinle Ekiti. Akara oyinbo yii ni awon tisa fi da lola.
Read More »admin Comments Off on Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada
Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe ...
Read More »admin Comments Off on Akoni osere onitiata: Bimbo Thomas gbayi!
Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata ...
Read More »admin Comments Off on Dapo Lam Adesina n fo lo si ilu Jamani
Omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, to tun je okan lara awon omo ile igbimo asoju-sofin ilu Abuja, Dapo Lam Adesina ti n gbera lo si ilu Jamani bayii lati lo yanju awon akanse ise ilu ti won gbe ...
Read More »admin Comments Off on Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara
Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. Bakan naa ni awon onise tiata kii fe ...
Read More »admin Comments Off on Awon wo ni Kunle Afolayan sepe fun?
Ogbontarigi onise tiata, Kunle Afolayan ti fepe ranse fun awon ti kii ra ojulowo fiimu ti won se sita, to je wi pe ayederu ti awon onisedudu n se ni won ra. “To o ba ra ayederu sinima mi tabi ...
Read More »admin Comments Off on “Ile ise MTN le kogba wole ti won ba sawon itanran tijoba pase re” – Minisita
Minisita tuntun fun eto ibanisoro, Ogbeni Bayo Shittu ti so wi pe ile ise MTN eka ti orileede Naijiria le kogba wo le ti won ba san owo itanran ti ajo ti n risi eto ibanisoro, Nigerian Communications Commission (NCC) ...
Read More »admin Comments Off on Opin ti de ba ogbologbo olosa ti n gbe alabahun saya jale
Opin ti de ba ogbologbo olosa ti n gbe alabahun saya jale Olayemi OlatilewaOwo awon olopaa digboluja ti a mo si Special Anti Robbery Squad (SARS) ti ipinle Kogi ti te ogbologbo olori awon adigunjale afurasi kan ti n lo ...
Read More »admin Comments Off on Deji Akure ti won yo loye ti gbe Ijoba ipinle Ondo lo sile ejo
Leyin odun marun-un ti ijoba ipinle Ondo ro Adesina Adepoju loye gege bi Deji tilu Akure, oba ilu Akure nigba kan ri naa ti gbe ejo dide ni kootu lati gba ade re pada. Ojo kewaa osu kefa odun 2010 ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more