Home / Art / Àṣà Oòduà / Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?

Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?

Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, won ri wi pe won ti yo oju re sa lo.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event

Live Event Video: The Coronation of The 21st Olu of Warri

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event