Eni odun ba ba laye, e pe ko sope. Eni Edua oke ba dasi, e pe ko ke aleluya s’Olorun Oba. Ojo nla ni ojo oni je, ojo kejila osu kokanlan odun, ojo ti Omidan Awelewa Amoke, Oba Oge Eleyinju-ege ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Leta ife jade lojo ti Olamide Orente se ojo-ibi alarinrin
Eni odun ba ba laye, e pe ko sope. Eni Edua oke ba dasi, e pe ko ke aleluya s’Olorun Oba. Ojo nla ni ojo oni je, ojo kejila osu kokanlan odun, ojo ti Omidan Awelewa Amoke, Oba Oge Eleyinju-ege ...
Read More »admin Comments Off on Gobe Sele Nigba Ti Omo Yari Wi Pe Oun o ni fohin
Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti ...
Read More »admin Comments Off on Yinka Ayefele ti pada sile orin: Keresimesi odun yii ma minringindin
Yinka Ayefele ti pada sile orin: Keresimesi odun yii ma minringindin Olayinka Joel Ayefele ti pada si yara agbara orin lati gbe orin tuntun jade fun awon ololufe re kari aye. Gege bi awon ololufe orin Gospel Tungba se mo, ...
Read More »admin Comments Off on Ambode naa ti pada si ni se bi Fayose: Gomina Eko ti pada sigboro aye
Gomina Akinwumi Ambode lo da awako akero kan ti n wa moto lona aito duro lonii nigboro Eko. Se kii se wi pe gomina naa fe ma se bi Ogbeni Ayodele Fayose?
Read More »admin Comments Off on Ojo-ibi oniroyin to gbamuse: Femi Davies, okunrin ogun
Oni ni ojo ibi Ogbeni Femi Davies, alase ati oludari MetroNews Nigeria. Igba odun, odun kan ni.
Read More »admin Comments Off on Omo yibo sepe fun Yoruba lori oro Biafra ti won fe da sile
Awon omo Yibo ti bere si ni soko oro si iran Yoruba to ri wi pe won fe pin kuro ninu orileede Naijiria. Won fe da Biafra sile, won ni awon ko ba Naijiria se mo. E dakun, e wo ...
Read More »admin Comments Off on Awon ologun yibon fun okan lara awon to pe fun Biafra ni Pota lonii
Leyin ti awon omo ologun yinbon pa okan lara awon oluwode ti won pe fun idasile Biafra, ibon tun ba okan lara won lonii niluu PORT HARCOURT.
Read More »admin Comments Off on Ilu Amerika gbalejo Goodluck Jonathan
Ilu Amerika ti gbalejo Aare ile Naijiria nigba kan ri, GOODLUCK JONATHAN si Challotsville to wa ni Virginia latari igbelaruge ijoba awarawa re ati gbigbe ijoba sile ni woorowo. Ogbeni Jonathan lo sokale siluu Amerika lojo aje ana. Lati Ọwọ ...
Read More »admin Comments Off on Lobatan: Won ti n ge tomato lori foonu chinco
Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso. Won ni to ...
Read More »admin Comments Off on Igo dudu meta: Toyin Aimakhu, Muyiwa Ademola ati Eniola Badmus
E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more