Home / Art / Àṣà Oòduà / “E ma fi mi we Messi mo”- C. Ronaldo
ronaldo

“E ma fi mi we Messi mo”- C. Ronaldo

Ogbontarigi agbaboolu Real Madrid, Christiano Ronaldo ti ro awon ololufe ere boolu agbaye lati dekun ati maa fi we akegbe re lati inu egbe agbaboolu Barcelona, Lionel Messi.Bi o tile je wi pe gbogbo awon ololufe ere boolu ki i ye gbe awon akoni ori odan meji naa yewo sira won, sugbon lenu ojo meta yii ni awuyewuye naa tun ru jade bi omi seleru eleyii to gba gbogbo iroyin agbaye kankan.
“Oun ni sitayi tie, emi naa ni sitayi temi. Bi awon eniyan se n fi wa wera wa ko je tuntun si mi mo.Sugbon lopo igba mi-in awon iroyin naa maa n ta mi leti nitori ohun kan naa ni awon eniyan n ran monu ni gbogbo igba”– C. Ronaldo
Olayemioniroyin.com

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Quadri Akinade Aruna vs Hugo Calderano

Quadri Akinade Aruna vs Hugo Calderano | MS R16 | WTT Finals Men Doha 2023