Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife
Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.
Read More »admin Comments Off on Mama o fe e gba: Iyabo Ojo ati omo re
Edumare ma pa omo folomo. Ti eniyan ba ri omo Iyabo Ojo, eniyan le sebi boya aburo re ni. Iya gan-an ni ko si fe gba yii. Oga ju!
Read More »ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o.. Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an ...
Read More »admin Comments Off on Madueke ko ti bo ninu ejo, Ile ejo ko fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC
Madueke o ti bo ninu ejo, Ile ejo o fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC Olayemi Olatilewa Ile ise ti n risi iwa idaran niluu London, National Crime Agency [NCA] si n ba iwadii won lo ni ...
Read More »Leyin ayeye ojo ibi odun metadinlogorin (77) Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III to waye laipe yii, awon ojongbon tun ti pawopo fi oye Dokita da Alaafin Oyo lola. Ayeye yii lo waye l’Ojoru to koja yii nibi won ti ...
Read More »admin Comments Off on Olise dubule aisan leyin ti Emmanuel Emenike dagbere fun egbe Super Eagles
Akoni-moogba egbe agbaboolu Naijiria, Sunday Oliseh ni won ti gbe digbadigba lo si ilu Belgium bayii fun itoju. Ajo ti n dari ere boolu Naijiria, The Nigeria Football Federation lo so eleyii di mimo loju opo won [@thenff] eleyii to ...
Read More »admin Comments Off on Ladoja setan lati gba ipo gomina pada lowo Ajimobi ni kootu
Ladoja ati Ajimobi: Taani ipo gomina yoo ja mo lowo ni kootu? Oniroyin: Olayemi Olatilewa Orisun Oniroyin: Twitter Nibayii, won ti kede ojo ti won yoo pari ejo, eleyii ti o je asekagba, to wa laaarin Senato Rasheed Adewolu Ladoja ...
Read More »admin Comments Off on Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan
Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan Orisun Oniroyin: Twitter Ile ejo Majisireeti ti n jokoo niluu Ibadan ti ran Ogbeni Sunday Jimoh lewon bayii leyin igba to fi ehin ja ...
Read More »admin Comments Off on Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata
Orisun Oniroyin Twitter Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata *Didake David Mark n ko awon eniyan lominu *Asa tuntun ti won da: “Mi o gba riba ri laye mi” – Amaechi “Gege bi gomina, mi ...
Read More »admin Comments Off on Ewi Awon Omode: E Ma Ya Baseje
Ewi: E ma ya baseje Eyin ewe iwoyii, e wa teti si agogo ogbon E ma ya baseje Baseje ti n bale je ni won pe larungun Arungun ni eni ti n ba ohun ti won fowo se je ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more