Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi
Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo ...
Read More »admin Comments Off on E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba
Laaarin ile itaja nla kan niluu Warri, bobo yii kunle fun ololufe re. O mu oruka ife jade lapo, o si wi bayii wi pe: “Joo ololufe mi, nje o gba lati je iyawo mi?” Opolopo awon eniyan ti won ...
Read More »admin Comments Off on Awon eniyan ti bere si ni fi adura ranse si oga @DeleMomodu
@DeleMomodu, okan ninu awon oga oniroyin ile Naijeria, eni ti pupo ninu awon akegbe re feran lati maa pe ni Bob Dee, ni okan ninu oju meji re n yo lenu bayii. Won ti se ise abe fun adari ati ...
Read More »admin Comments Off on Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika
Won ti so mi lenu, idi ni yii ti mo fi pinnu lati dake. Won ti fabuku kan mi, idi ni yii ti mo fi senu mi ni deede sibi. Awon kan tile leri wi pe maa kandin ninu iyo, ...
Read More »admin Comments Off on Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun
Orisun Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun Olayemi Olatilewa Ile igbimo asofin Ipinle Kwara ti kede ogunjo osu kewaa odun yii [20/10/15]gege bi ojo ti won yoo se agbeyewo awon komisanna tuntun ti gomina ...
Read More »admin Comments Off on Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.
Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin ...
Read More »admin Comments Off on Awon olopaa gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki.
Orisun Awon olopaa fako yo! Won gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki. Olayemi Olatilewa Awon olopaa digboluja ti won gbogun ti iwa odaran gba obitibiti owo naira pada lowo awon adigunjale ti won dena ...
Read More »admin Comments Off on Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo
Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. ...
Read More »admin Comments Off on Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode
Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade ...
Read More »admin Comments Off on Omo yibo yari mo awon omo ile igbimo asofin Eko lowo.
Omo yibo yari mo awon omo ile igbimo asofin Eko lowo. *O ni oun o fara mo siso ede Yoruba nile igbimo asofin Onarebu Jude Idimogu, okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko, ti tako aba ile lati ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more