Tai Solarin dilu nla Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla. Ibi ọgbọn gbe pamọ si. Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke. Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki. Kinihun o jẹran ikaṣi. To ba jọ bi irọ, ...
Read More »Olopaa Ko Le Mu…
Okan lara awon aworan to jade lati ipinle Bauchi sori ayelukara lojo odun ileya to koja ni yii. Lotito, olopaa ko le mu won. Nitori olopaa kan wo won lotito ko si le da won duro. Sebi odun lo de.
Read More »Enu Kofi Omo Ghana Pada Re Ba a Lese
Eyin eniyan mi, ohun kan se pataki ti mo fe ko da wa loju; ti mo si fe ki oye re ye wa gidi. Igbe aye eniyan wa ninu oro siso tabi ohun ti a fenu se ijewo re. Iru ...
Read More »Ogo Omu-Aran Ni Ipinle Kwara Pe Eni Odun Mokanlelogota (61)
Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro ...
Read More »Won Ya Aso Iyi Saraki Niluu Ilorin Lojo Odun Ileya
Okuta ati ogulutu ni awon eniyan bere si ni so lu aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, laaaro oni nibi to ti fe kirun yidi odun ileya niluu Ilorin Afonja. Bi awon eniyan se n ju okuta bee naa ...
Read More »Kilode Ti Ogbeni Bukola Saraki Fi N Paro?: O paro Nile Ejo Tiribuna, O Tun Paro Fun Omo Naijeria
Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...
Read More »Se Eyin Ri Iru Aso Igbeyawo Bayii Ri?
E leyii tun leku!
Read More »Ohun Ti E Ko Mo Nipa Igbeyawo Obasanjo Ati Iyawo Re, Mama Iyabo
Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...
Read More »Foto Yii Lo N Se Afihan Ohun Ti Awon Omo Nigeria N Ro Nipa Ojo Ola Nigeria
Nje awon eniyan omo Nigeria si ni igbagbo wi pe Naijeria sile goke agba? E se ayewo linki isale yii lati ka ero awon omo Nigeria:
Read More »Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)
Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ...
Read More »