Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Kilode Ti Ogbeni Bukola Saraki Fi N Paro?: O paro Nile Ejo Tiribuna, O Tun Paro Fun Omo Naijeria
Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...
Read More »admin Comments Off on Se Eyin Ri Iru Aso Igbeyawo Bayii Ri?
E leyii tun leku!
Read More »admin Comments Off on Ohun Ti E Ko Mo Nipa Igbeyawo Obasanjo Ati Iyawo Re, Mama Iyabo
Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...
Read More »admin Comments Off on Foto Yii Lo N Se Afihan Ohun Ti Awon Omo Nigeria N Ro Nipa Ojo Ola Nigeria
Nje awon eniyan omo Nigeria si ni igbagbo wi pe Naijeria sile goke agba? E se ayewo linki isale yii lati ka ero awon omo Nigeria:
Read More »admin Comments Off on Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)
Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ...
Read More »admin Comments Off on Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun
Won ti bere igbaradi, inu osu kokanla odun yii ni won pinnu lati se ojo ibi Ogorun (100) Odun Yeye Oodua. Sugbon iku seka, iku doro, iku mu Hannah Idowu Dideolu Awolowo lo leni odun mokandinlogorun (99). Ki Edua oke ...
Read More »admin Comments Off on Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada ‘geti’ Maanu Naa
Leyin awon esun bi metala ati esun iro funfun ti Bukola Saraki pa nipa jijewo dukia to ni. Ile ise ijoba apapo, eka ti awon onidajo ti pase ki ile ise olopaa ile yii, labe akoso ogbeni Solomon Arase lo ...
Read More »admin Comments Off on Irawo Olorin Ti Won Yin Ni Bajinatu Lodun 2007 Ti Pe Omo Ogoji (40) Odun Lonii
Osu kewaa odun 2007 ni awon afura si kan gege bi agbanipa bere si ni rojo ibon fun Innocent Idibia ni ibudoko Cele to wa loju ona masose Oshodi si Apapa to wa niluu Eko. Sugbon gege bi Ayinla Omowura ...
Read More »admin Comments Off on E Wa Wo Ohun Ti Won Se Fun Ole Ti Won Mu N’Ikeja
Ole ti won mu ni agbegbe Ikeja ni yii losan-an ana. Awon eniyan se idajo owo won fun-un lai duro de awon olopaa. Nje o dara ki a maa se idajo owo wa fun awon odaran tabi ki a maa ...
Read More »Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more