Home / Art / Àṣà Oòduà (page 159)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

E jowo e lami loye Omo Oodua rere !

Tani Egbon ninu OWO…… ati IMO……

Read More »

Ki Loruko Arakunrin Wa yi ??

Omo Iluwo ni Se ?

Read More »

Aworan Yii Kiise Aroso Rara !

Bi Mi O Tie Mo Iyawo, Sugbon Mo Mo Oko Pelu Ise-owo Re, Isele Aburu Yi Waye Ni Ilu Ilogbo Ota, Ni Ipinle Ogun. Oko (Morufu Olasoji) Nfi Esun Agbere Kan Iyawo Re Kehinde Olasoji, Pelu Igbonara, Oko Lu Iyawo ...

Read More »

Odu Ifa: Obara eguntan

Obara eguntan I I I II I II II II Ifa so wipe ki alaniyan yi ni aforiti gidigidi lori ohun ti o difa si yi. Obara eguntan, egun kun, ajapa-nlele A difa fun agunfon-abi-osulolo Nijo ti I nbe l’oko ...

Read More »

Odu Ifa: Obara gbedipon

Obara gbedipon I I II II II II I II Eni odu ifa yi ba wa fun ifa kilo pe ko kiyesi awon iwa owo re gidigidi M’omode ole, maa m’agba ole, agba ole soro mu l’oko Adifa fun obara ...

Read More »

Edumare Je ki aje wa emi ati iwo rii….ase

Ase !!

Read More »

Check out Oriki and songs book on Osun, Olokun

Oriki and songs book on Osun,Olokun,Egbe,Oya and Sango on songs and chant by Iyalorisa Oyelola Elebuibon Package by Ifayemisi Elebuibon. The book is in Yoruba with English translations.  Each purchase qualify for one person 1hr free tutor class with Ifayemisi ...

Read More »

Nje Iwo Tiri Iru Igbeyawo Eleyi Ri ?

Ni ile aye tabi kani ni Nigeria wa yi orisirisi lama ma ri. Ni Nigeria wa yi na loti sele, O’ku osu meji ti awon toko taya yi dajo Igbeyawo won ni Oko Iyawo wan ni atimole awon olopa ni ...

Read More »

Oruko wo loye kafun ?

Read More »

AWO YO’OOBA 101 – Part 1 ( Must Read/Learn for Every Yo’ooba Man/Woman)

1. AWO YORUBA THE LANGUAGE OF IFÁ GLOSSARY OF TERMS USED IN IFÁ DIVINATION Awo Fa’lokun Fatunmbi Egbe Iwa Pele 2. Introduction In order to understand the oral tradition of Ifa it is necessary to have some grasp of the ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb