Home / Art / Àṣà Oòduà (page 164)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Moki gbogbo eyin Omo oodua pe asiku imura idibo tinbo yi

Eje kasora dada oledumare  koni fi aburu kan wa .ki okunrin merin 4 ki oso eni ti afe ki owa lori aga agba loke loun .ki obirin merin 4 na funwa ni ti won .awon agba ni oun eyan loun oun ...

Read More »

Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !

ORIKI ORILE IREMOGUN:-Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro. Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni. Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon ...

Read More »
esu

Esu lalu okiri oko okiri ! (police of the universe)

Esu lalu okiri oko okiri ogo(police of the universe) ako ebo ti ofi orita se afin.Laroye ebora ti ron oju mo omo kinkankinkan. Esu mase mi omo elomi ni kose……….n.

Read More »

Oriki Olodumare !

Olubabi Ifaniyi Power

Read More »

Oro kan fun odaju abiyamo !

Eku ojumo esinku isimi oni,besini esin tun ku oro ilu, hmm awon yoruba ama paalowe wipe eniyo npanu eni ebinpanranku,Ewo omo tuntun jojolo yi nibi ti wonsonu si ninu poli bagi,sugbon osemilanu wipe omo natidagbere faye bayi ni oni paanu ...

Read More »

E ba mi fun won loruko kan

Read More »

Oruko Woni Kokoro yi nje ni Ile Yoruba ?

Read More »

Eledumare iba re loni o…

Eledumare iba re loni o,akoda aiye iba,aseda aiye iba,baba mi odetunde iba re loni o,iya mi iba re,iba oluwo ,iba iya nifa,iba olojo oni, aku ose ogun o,ogun yio bawa se o,ao ni tele lodi,ogun yio la ona fun wa ...

Read More »

Awon èyà Yorùbá wo lo ma n ko irú Ilà yìí?

Awon èyà Yorùbá wo lo ma n ko irú Ilà yìí?

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb