Iya mi Osun Sengese Ladekoju Ebora ti n gbenu omiLagbolodo,Iwo ni mo nkee si o.Osun ma n bo oYago lona o.
Read More »Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!
Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...
Read More »Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn
Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo
Read More »Ìwúre Toni
Ikú tó yọ lóòré ńkọ́ Àrùn tó yọ lóòré ńkọ́ Ẹjọ́ tó yọ lóòré ńkọ́ Òfò tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí kọ̀wun, àyà mí kọ̀wunMoti jẹ kọ̀ǹkọ̀ mo ti kọ̀ Owó,aya, ọmọ,gbogbo ire tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí gbàwun, àyà mí gbàwunMoti jẹ ...
Read More »O lápátí
Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...
Read More »E ku Ose Ifa
Aráká-AjagaAràkà-AjagaAdifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin ÈdúÈnìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè MejiAráká-Oku-AjagaAràkà-Oku-Ajaga ??Ase Tedumare?? ?Ifabukky Care?
Read More »Ìgbín
Àkòrò ní ìgbín fà gungi Ìgbín kò lọ́wọ́ Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀ Àkòrò ní ìgbín fà gungi Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní já sófo
Read More »ERÍWO YÀ! ERÍWO YÀ!! ERÍWO YÀ!!!
Gbogbo ẹ̀yin Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀; Ojú rẹ rèé o : Babaláwo Babájídé Ọ̀ṣúnníyì (Olúwo Jọ̀gbọ̀dọ́ Ọ̀rúnmìlà). Ní òní yìí ni ìgbẹ́jọ́ ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà sí ìdí Ifá / Ìṣẹ̀ṣe (lẹ́yìn ikú Baba rẹ ní ...
Read More »OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn.
OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn. Àwon alámòójútó àti akékòó ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo University ti ilé- ife, máa péjo sí gbàgede Amphitheater tí ilé èkó ...
Read More »Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..
Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...
Read More »